Psalms 122:9
“Nítorí ilé Olúwa Ọlọ́run wa, èmi yóò máa wá ìre rẹ̀.”
Psalms 122:9 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 9 of 9 in Psalms chapter 122 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Psalms 122 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ sílé Olúwa.” Ẹsẹ̀ wa yóò dúró ní ẹnu ibodè rẹ, ìwọ ẹmu. Jerusalẹmu, ìwọ tí a kọ́ bí ìlú tí o fi ara mọ́ra pọ̀ ṣọ̀kan. Níbi tí àwọn ẹ̀yà máa ń gòkè lọ, àwọn ẹ̀yà Olúwa, ẹ̀rí fún ẹli, láti máa dúpẹ́ fún orúkọ Olúwa. Nítorí ibẹ̀ ni a gbé ìtẹ́ ìdájọ́ kalẹ̀, àwọn ìtẹ́ ilé . Gbàdúrà fún àlàáfíà ẹmu; àwọn tí ó fẹ́ ọ yóò ṣe rere. Kí àlàáfíà kí ó wà nínú odi rẹ̀, àti ìre nínú ààfin rẹ̀. Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mi èmi yóò wí nísinsin yìí pé, kí àlàáfíà kí ó wà nínú rẹ̀. Nítorí ilé Olúwa Ọlọ́run wa, èmi yóò máa wá ìre rẹ̀.
Every verse in Psalms 122
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.