Saamu

Saamu 83

Psalm 83 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 83Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading names Asaph as its author. This is a lament Psalm that asks God to act against a coalition of hostile nations.

Saamu 83 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ọlọ́run, má ṣe dákẹ́; má ṣe dákẹ́, Ọlọ́run má ṣe dúró jẹ́ẹ́.

KJV verse 1: Keep not thou silence, O God: hold not thy peace, and be not still, O God.

Wo bí àwọn ọ̀tá rẹ ti ń rọ́kẹ̀kẹ̀ lọ, bi àwọn ọ̀tá rẹ ti ń gbé ohùn wọn sókè.

KJV verse 2: For, lo, thine enemies make a tumult: and they that hate thee have lifted up the head.

Pẹ̀lú àrékérekè ni wọn dìtẹ̀ sí àwọn ènìyàn rẹ; wọn sí dìtẹ̀ mọ́ àwọn tí o fẹ́.

KJV verse 3: They have taken crafty counsel against thy people, and consulted against thy hidden ones.

Wọn wí pé, “wá, ẹ jẹ́ kí á pa wọ́n run bí orílẹ̀-èdè, kí orúkọ ẹli ma bá a sí ní ìrántí mọ́.”

KJV verse 4: They have said, Come, and let us cut them off from being a nation; that the name of Israel may be no more in remembrance.

Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú ọkàn kan; wọ́n ṣe àdéhùn láti ṣọ̀tẹ̀ sí ọ

KJV verse 5: For they have consulted together with one consent: they are confederate against thee:

Àgọ́ àti ti àwọn ará Iṣmaeli, ti àti ti

KJV verse 6: The tabernacles of Edom, and the Ishmaelites; of Moab, and the Hagarenes;

Gebali, Ammoni àti , Filistia, pẹ̀lú àwọn ènìyàn .

KJV verse 7: Gebal, and Ammon, and Amalek; the Philistines with the inhabitants of Tyre;

Asiria pẹ̀lú ti darapọ̀ mọ́ wọn láti ran àwọn ọmọ Lọti lọ́wọ́. .

KJV verse 8: Assur also is joined with them: they have holpen the children of Lot. Selah.

Ṣe sí wọn bí ìwọ ti ṣe sí bí o ti ṣe sí àti ní odò Kiṣoni,

KJV verse 9: Do unto them as unto the Midianites; as to Sisera, as to Jabin, at the brook of Kison:

ẹni tí ó ṣègbé ní tí wọn sì dàbí ààtàn ní orí ilẹ̀.

KJV verse 10: Which perished at Endor: they became as dung for the earth.

Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí àti , àwọn ọmọ-aládé wọn bí àti ,

KJV verse 11: Make their nobles like Oreb, and like Zeeb: yea, all their princes as Zebah, and as Zalmunna:

tí ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a gbà ní ìní àní pápá oko tútù Ọlọ́run.”

KJV verse 12: Who said, Let us take to ourselves the houses of God in possession.

Ìwọ Ọlọ́run, ṣe wọ́n bí ààjà, bí ìyàngbò níwájú afẹ́fẹ́.

KJV verse 13: O my God, make them like a wheel; as the stubble before the wind.

Bí iná ti í jó igbó, àti bí ọ̀wọ́-iná ti ń mú òkè ńlá gbiná,

KJV verse 14: As the fire burneth a wood, and as the flame setteth the mountains on fire;

bẹ́ẹ̀ ni kí o fi ẹ̀fúùfù líle rẹ lépa wọn dẹ́rùbà wọn lójú pẹ̀lú ìjì rẹ.

KJV verse 15: So persecute them with thy tempest, and make them afraid with thy storm.

Fi ìtìjú kún ojú wọn, kí àwọn ènìyàn bá à lè ṣe àfẹ́rí orúkọ rẹ àti kí o fi ìjì líle rẹ dẹ́rùbà, ìwọ Olúwa.

KJV verse 16: Fill their faces with shame; that they may seek thy name, O LORD.

Jẹ́ kí ojú kí ó tì wọ́n, kí wọ́n sì dààmú láéláé kí wọ́n ṣègbé sínú ẹ̀gàn

KJV verse 17: Let them be confounded and troubled for ever; yea, let them be put to shame, and perish:

jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa: pé ìwọ nìkan ní Ọ̀gá-ògo jùlọ lórí gbogbo ayé.

KJV verse 18: That men may know that thou, whose name alone is JEHOVAH, art the most high over all the earth.

Every verse in Saamu 83

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 830:00 / 0:00