Saamu

Saamu 87

Psalm 87 in Yoruba and English (KJV) · Orin Dafidi 87Tap any highlighted word for context

About this Psalm

The Psalm heading names the sons of Korah as its authors. This is a praise Psalm that celebrates Zion and God's welcome of people from the nations.

Saamu 87 — Scripture text (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ó ti fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkè mímọ́;

KJV verse 1: His foundation is in the holy mountains.

Olúwa fẹ́ràn ẹnu-ọ̀nà ju gbogbo ibùgbé ọbu lọ.

KJV verse 2: The LORD loveth the gates of Zion more than all the dwellings of Jacob.

Ohun ológo ni a sọ nípa rẹ̀, ìlú Ọlọ́run,

KJV verse 3: Glorious things are spoken of thee, O city of God. Selah.

“Èmi ó dárúkọ àti láàrín àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi: Filistia pẹ̀lú, àti , pẹ̀lú Kuṣi, yóò sọ pé, ‘Èyí ni a bí ní .’ ”

KJV verse 4: I will make mention of Rahab and Babylon to them that know me: behold Philistia, and Tyre, with Ethiopia; this man was born there.

Nítòótọ́, ti ni a ó sọ, “Eléyìí àti eléyìí ni a bí nínú rẹ̀, àti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo ni yóò fìdí rẹ̀ múlẹ̀.”

KJV verse 5: And of Zion it shall be said, This and that man was born in her: and the highest himself shall establish her.

Olúwa yóò kọ nínú àkọsílẹ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀: “Eléyìí ni a bí ní .”

KJV verse 6: The LORD shall count, when he writeth up the people, that this man was born there. Selah.

Àti àwọn olórin àti àwọn tí ń lu ohun èlò orin yóò wí pé, “Gbogbo orísun mi ń bẹ nínú rẹ.”

KJV verse 7: As well the singers as the players on instruments shall be there: all my springs are in thee.

Every verse in Saamu 87

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

KJV: public domain

Most-read Psalms in Yoruba

Saamu 870:00 / 0:00