Psalms 87:5
“Nítòótọ́, ti Sioni ni a ó sọ, “Eléyìí àti eléyìí ni a bí nínú rẹ̀, àti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo ni yóò fìdí rẹ̀ múlẹ̀.””
Psalms 87:5 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 5 of 7 in Psalms chapter 87 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Psalms 87 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ó ti fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkè mímọ́; Olúwa fẹ́ràn ẹnu-ọ̀nà ju gbogbo ibùgbé ọbu lọ. Ohun ológo ni a sọ nípa rẹ̀, ìlú Ọlọ́run, “Èmi ó dárúkọ àti láàrín àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi: Filistia pẹ̀lú, àti , pẹ̀lú Kuṣi, yóò sọ pé, ‘Èyí ni a bí ní .’ ” Nítòótọ́, ti ni a ó sọ, “Eléyìí àti eléyìí ni a bí nínú rẹ̀, àti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo ni yóò fìdí rẹ̀ múlẹ̀.” Olúwa yóò kọ nínú àkọsílẹ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀: “Eléyìí ni a bí ní .” Àti àwọn olórin àti àwọn tí ń lu ohun èlò orin yóò wí pé, “Gbogbo orísun mi ń bẹ nínú rẹ.”
Every verse in Psalms 87
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.