1 Chronicles 18:3
“Síbẹ̀, Dafidi sì kọlu Hadadeseri ọba Soba ní Hamati, bí ó ti ń lọ láti fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ létí odò Eufurate.”
1 Chronicles 18:3 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 3 of 17 in 1 Chronicles chapter 18 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 18 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní àkókò kan, Dafidi kọlu àwọn ará , ó sì ṣẹ́gun wọn. Ó sì mú àti àwọn ìletò agbègbè rẹ̀ kúrò lábẹ́ ìdarí àwọn ará . Dafidi borí àwọn ará , wọ́n sì di ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì mú owó òde wá. Síbẹ̀, Dafidi sì kọlu ọba ní , bí ó ti ń lọ láti fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ létí odò . Dafidi fi agbára gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ rẹ̀, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) agun-kẹ̀kẹ́ àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) ológun ilẹ̀. Ó sì já gbogbo ọgọ́rùn-ún iṣan ẹsẹ̀ àwọn kẹ̀kẹ́-ẹṣin náà. Nígbà ti àwọn ará ti wá láti ran ọba lọ́wọ́, Dafidi lu ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) wọn bọ lẹ̀. Ó sì fi àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun rẹ sínú ìjọba ti , àwọn ará sì ń sìn ní abẹ́ rẹ̀, wọ́n sì mú owó ìṣákọ́lẹ̀ wá. Olúwa sì ń fún ní ìṣẹ́gun ní ibi gbogbo tí ó bá lọ. Dafidi mú àpáta wúrà tí àwọn ìjòyè gbé, ó sì gbé wọn wá sí ẹmu. Láti àti , àwọn ìlú , Dafidi kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ idẹ tí lò láti fi ṣe okùn idẹ, àwọn òpó àti oríṣìí ohun èlò idẹ. Nígbà tí ọba gbọ́ pé ti borí gbogbo ọmọ-ogun ọba . Ó rán ọmọ rẹ̀ sí ọba láti kí i àti láti lọ bá a yọ̀ lórí ìṣẹ́gun rẹ̀ nínú ogun lórí , tí ó wà lójú ogun pẹ̀lú . Hadoramu mú oríṣìíríṣìí ohun èlò ti wúrà àti fàdákà àti idẹ wá. Ọba ya ohun èlò wọ́n yí sí mímọ́ fún Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe pẹ̀lú fàdákà àti wúrà tí ó ti mú láti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí: Edomu àti , ará àti àwọn ará àti . Abiṣ ọmọ lu ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ará bolẹ̀ ní àfonífojì Iyọ̀. Ó fi ẹgbẹ́ ogun sí , gbogbo àwọn ará sì ń sìn ní abẹ́ . Olúwa fún ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibí tí ó bá lọ. Dafidi jẹ ọba lórí gbogbo ẹli, ó sì ṣe òdodo àti ohun tí ó yẹ fún gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀. Joabu ọmọ jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ-ogun; Jehoṣafati ọmọ jẹ́ akọ̀wé ìrántí; Sadoku ọmọ àti ọmọ jẹ́ àwọn àlùfáà; Ṣafṣa jẹ́ akọ̀wé; Benaiah ọmọ jẹ́ olórí àwọn àti ; àwọn ọmọ sì ni àwọn olóyè íṣẹ́ ní ọ̀dọ̀ ọba.
Every verse in 1 Chronicles 18
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.