1 Chronicles 20:7
“Nígbà tí ó fi Israẹli ṣẹ̀sín, Jonatani ọmọ Ṣimea, arákùnrin Dafidi sì pa á.”
1 Chronicles 20:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 8 in 1 Chronicles chapter 20 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
1 Chronicles 20 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ní àkókò àkọ́rọ̀ òjò, ni ìgbà tí àwọn ọba lọ sí ogun, Joabu ṣamọ̀nà àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun. Ó fi ilẹ̀ àwọn ará ṣòfò. Ó lọ sí ọ̀dọ̀ . Ó sì fi ogun dúró tì í. Ṣùgbọ́n dúró sí ẹmu kọlu , ó sì fi sílẹ̀ ní ìparun. Dafidi mú adé kúrò lórí àwọn ọba wọn ìwọ̀n rẹ̀ dàbí i tálẹ́ǹtì wúrà, a sì tò ó jọ pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye. A sì gbé e ka orí . Ó kó ọ̀pọ̀ ìkógun láti ìlú ńlá náà. Ó sì kó gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà ní ibẹ̀ jáde, ó sì fi iṣẹ́ lé wọn lọ́wọ́ láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ayùn àti ìtulẹ̀ írin àti àáké. Dafidi ṣe eléyìí sí gbogbo àwọn ará ìlú . Nígbà náà, Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ padà sí ẹmu. Ní ẹ̀yìn èyí ni ogun bẹ́ sílẹ̀ ní pẹ̀lú àwọn ará , ní àkókò yìí ni ará Huṣati pa , ọ̀kan lára àwọn ọmọ , àti àwọn ará ni a ṣẹ́gun. Nínú ogun mìíràn pẹ̀lú àwọn ará , Elhanani ọmọ pa arákùnrin ará , ẹni ti ó ní ọ̀kọ̀ kan tí ó dàbí ọ̀pá ahunṣọ. Síbẹ̀síbẹ̀ nínú ogun mìíràn, tí ó wáyé ní , ọkùnrin títóbi kan wà tí ó ní ìka mẹ́fà ní ọwọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ìka mẹ́fà ní ẹsẹ̀ rẹ̀ mẹ́rìnlélógún lápapọ̀. Òun pẹ̀lú wá láti . Nígbà tí ó fi ẹli ṣẹ̀sín, Jonatani ọmọ Ṣimea, arákùnrin sì pa á. Wọ̀nyí ni ìran ọmọ ní , wọ́n sì ṣubú sí ọwọ́ àti àwọn ọkùnrin rẹ̀.
Every verse in 1 Chronicles 20
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.