Joshua 10:27

“Nígbà tí oòrùn wọ̀, Joṣua pàṣẹ, wọ́n sì sọ̀ wọ́n kalẹ̀ kúrò ní orí igi, wọ́n sì gbé wọn jù sí inú ihò àpáta ní ibi tí wọ́n sá pamọ́ sí. Wọ́n sì fi òkúta ńlá dí ẹnu ihò náà, tí ó sì wà níbẹ̀ di òní yìí.”

Joshua 10:27 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible

Verse 27 of 43 in Joshua chapter 10 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.

Joshua 10 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)

Ní báyìí tí - ọba ẹmu gbọ́ pé Joṣua ti gba , tí ó sì ti pa wọ́n pátápátá; tí ó sì ṣe sí àti ọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí àti ọba rẹ̀, àti bí àwọn ènìyàn ti ṣe àdéhùn àlàáfíà pẹ̀lú ẹli, tí wọ́n sì ń gbé nítòsí wọn. Ìbẹ̀rù sì mú òun àti àwọn ènìyàn rẹ̀ torí pé jẹ́ ìlú tí ó ṣe pàtàkì, bí ọ̀kan nínú àwọn ìlú ọba; ó tóbi ju lọ, gbogbo ọkùnrin rẹ̀ ní ó jẹ́ jagunjagun. Nítorí náà - ọba ẹmu bẹ ọba , Piramu ọba , Jafia ọba ṣi àti ọba . Wí pe, “Ẹ gòkè wá, kí ẹ sì ràn mi lọ́wọ́ láti kọlu , nítorí tí ó ti wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú Joṣua àti àwọn ará ẹli.” Àwọn ọba márààrún, ọba ẹmu, Hebroni, Jarmatu, Lakiṣi àti , kó ara wọn jọ, wọ́n sì gòkè, àwọn àti gbogbo ogun wọn, wọ́n sì dojúkọ , wọ́n sì kọlù ú. Àwọn ará sì ránṣẹ́ sí Joṣua ní ibùdó ní pé, “Ẹ má ṣe fi ìránṣẹ́ yín sílẹ̀. Ẹ gòkè tọ̀ wà wá ní kánkán kí ẹ sì gbà wá là. Ẹ ràn wá lọ́wọ́, nítorí gbogbo àwọn ọba tí ń gbé ní orílẹ̀-èdè òkè dojú ìjà kọ wá.” Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua gòkè lọ láti pẹ̀lú gbogbo ogun rẹ̀, àti akọni nínú àwọn ọmọ-ogun rẹ̀. Olúwa sì sọ fún Joṣua pé, “Má ṣe bẹ̀rù wọn, Mo ti fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́. Kò sí ẹnikẹ́ni nínú wọn ti yóò lè dojúkọ ọ́.” Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti wọ́de ogun ní gbogbo òru náà láti , Joṣua sì yọ sí wọn lójijì. Olúwa mú kí wọn dààmú níwájú àwọn ẹli, wọ́n sì pa wọ́n ní ìpakúpa ní . Israẹli sì lépa wọn ní ọ̀nà tí ó lọ sí -, ó sì pa wọ́n dé , àti . Bí wọ́n sì tí ń sá ní iwájú ẹli ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ ní ọ̀nà láti - títí dé , Olúwa rọ yìnyín ńlá sí wọn láti ọ̀run wá, àwọn tí ó ti ipa yìnyín kú sì pọ̀ ju àwọn tí àwọn ará ẹli fi idà pa lọ. Ní ọjọ́ tí Olúwa fi àwọn ọmọ lé ẹli lọ́wọ́, Joṣua sọ fún Olúwa níwájú àwọn ará ẹli, “Ìwọ oòrùn, dúró jẹ́ẹ́ ní orí , Ìwọ òṣùpá, dúró jẹ́ẹ́ lórí àfonífojì .” Bẹ́ẹ̀ ni oòrùn náà sì dúró jẹ́ẹ́, òṣùpá náà sì dúró, títí tí ìlú náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ nínú ìwé Jaṣari. Oòrùn sì dúró ní agbede-méjì ọ̀run, kò sì wọ̀ ní ìwọ̀n odindi ọjọ́ kan. Kò sí ọjọ́ tí o dàbí rẹ̀ ṣáájú tàbí ní ẹ̀yìn rẹ̀, ọjọ́ tí Olúwa gbọ́ ohùn ènìyàn. Dájúdájú Olúwa jà fún ẹli! Nígbà náà ni Joṣua àti gbogbo ẹli padà sí ibùdó ní . Ní báyìí àwọn ọba márùn-ún ti sálọ, wọ́n sì fi ara pamọ́ nínú ihò àpáta kan ní , nígbà tí wọ́n sọ fún Joṣua pé, a ti rí àwọn ọba márààrún, ti ó fi ara pamọ́ nínú ihò àpáta ní , ó sì wí pé, “Ẹ yí òkúta ńlá dí ẹnu ihò àpáta náà, kí ẹ sì yan àwọn ọkùnrin sí ibẹ̀ láti ṣọ́ ọ. Ṣùgbọ́n, ẹ má ṣe dúró! Ẹ lépa àwọn ọ̀tá yín, ẹ kọlù wọ́n láti ẹ̀yìn, kí ẹ má ṣe jẹ́ kí wọn kí ó dé ìlú wọn, nítorí tí Olúwa Ọlọ́run yín tí fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.” Bẹ́ẹ̀ ní Joṣua àti àwọn ọmọ ẹli pa wọ́n ní ìpakúpa wọ́n sì pa gbogbo ọmọ-ogun àwọn ọba márààrún run, àyàfi àwọn díẹ̀ tí wọ́n tiraka láti dé ìlú olódi wọn. Gbogbo àwọn ọmọ-ogun sì padà sí ọ̀dọ̀ Joṣua ní ibùdó ogun ní ní àlàáfíà, kò sí àwọn tí ó dábàá láti tún kọlu ẹli. Joṣua sì wí pe, “Ẹ ṣí ẹnu ihò náà, kí ẹ sì mú àwọn ọba márààrún jáde wá fún mi.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì mú àwọn ọba márààrún náà kúrò nínú ihò àpáta, àwọn ọba ẹmu, Hebroni, Jarmatu, Lakiṣi àti . Nígbà tí wọ́n mú àwọn ọba náà tọ Joṣua wá, ó pe gbogbo àwọn ọkùnrin ẹli, ó sì sọ fún àwọn olórí ọmọ-ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé, “Ẹ súnmọ́ bí, kí ẹ sì fi ẹsẹ̀ yín lé ọrùn àwọn ọba wọ̀nyí.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n wá sí iwájú, wọ́n sì gbé ẹsẹ̀ lé ọrùn wọn. Joṣua sì sọ fún wọn pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù, ẹ má sì ṣe fòyà. Ẹ ṣe gírí, kí ẹ sì mú àyà le. Báyìí ni Olúwa yóò ṣe sí gbogbo àwọn ọ̀tá yín, tí ẹ̀yin yóò bá jà.” Nígbà náà ni Joṣua kọlù wọ́n, ó sì pa àwọn ọba márààrún náà, ó sì so wọ́n rọ̀ ní orí igi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ márùn-ún, wọ́n sì fi wọ́n sí orí igi títí di ìrọ̀lẹ́. Nígbà tí oòrùn wọ̀, Joṣua pàṣẹ, wọ́n sì sọ̀ wọ́n kalẹ̀ kúrò ní orí igi, wọ́n sì gbé wọn jù sí inú ihò àpáta ní ibi tí wọ́n sá pamọ́ sí. Wọ́n sì fi òkúta ńlá dí ẹnu ihò náà, tí ó sì wà níbẹ̀ di òní yìí. Ní ọjọ́ náà Joṣua gba . Ó sì fi ojú idà kọlu ìlú náà àti ọba rẹ̀, ó sì run gbogbo wọn pátápátá, kò fi ẹnìkan sílẹ̀. Ó sì ṣe sí ọba gẹ́gẹ́ bí o ti ṣe sí ọba . Nígbà náà ní Joṣua àti gbogbo ẹli tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ kọjá láti lọ sí wọ́n sì kọlù ú. Olúwa sì fi ìlú náà àti ọba rẹ̀ lé ẹli lọ́wọ́. Ìlú náà àti gbogbo àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni Joṣua fi idà pa. Kò fi ẹnìkan sílẹ̀ ní ibẹ̀: Ó sì ṣe sí ọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí ọba . Nígbà náà ni Joṣua àti gbogbo ará ẹli, tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ kọjá láti lọ sí ṣi; ó sì dó tì í, ó sì kọlù ú. Olúwa sì fi ṣi lé ẹli lọ́wọ́, Joṣua sì gbà á ní ọjọ́ kejì. Ìlú náà àti gbogbo ènìyàn ibẹ̀ ní ó fi idà pa gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí . Ní àkókò yìí, Horamu ọba gòkè láti ran ṣi lọ́wọ́, ṣùgbọ́n Joṣua ṣẹ́gun rẹ̀ àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ títí ti kò fi ku ẹnìkan sílẹ̀. Nígbà náà ni Joṣua àti gbogbo ẹli tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ kọjá láti ṣi lọ sí ; wọ́n sì dó tì í, wọ́n sì kọlù ú. Wọ́n gbà á ní ọjọ́ náà, wọ́n sì fi ojú idà kọlù ú, wọ́n sì run gbogbo ènìyàn ibẹ̀ pátápátá, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe sí ṣi. Nígbà náà ni Joṣua àti gbogbo ẹli ṣí láti lọ sí , wọ́n sì kọlù ú. Wọ́n gba ìlú náà, wọ́n sì ti idà bọ̀ ọ́, pẹ̀lú ọba rẹ̀, gbogbo ìletò wọn àti gbogbo ènìyàn ibẹ̀. Wọn kò dá ẹnìkan sí. Gẹ́gẹ́ bí ti , wọ́n run un pátápátá àti gbogbo ènìyàn inú rẹ̀. Nígbà náà ni Joṣua àti gbogbo ẹli tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ yí padà, wọ́n sì kọlu . Wọ́n gba ìlú náà, ọba rẹ̀ àti gbogbo ìlú wọn, wọ́n sì fi idà pa wọ́n. Gbogbo ènìyàn inú rẹ̀ ni wọ́n parun pátápátá. Wọn kò sì dá ẹnìkankan sí. Wọ́n ṣe sí àti ọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí wọn ti ṣe sí àti ọba rẹ̀ àti sí . Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua ṣẹ́gun gbogbo agbègbè náà, ìlú òkè, gúúsù, ìlú ẹsẹ̀ òkè ti ìhà ìwọ̀-oòrùn àti gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè pẹ̀lú gbogbo ọba, wọn kò dá ẹnìkankan sí. Ó pa gbogbo ohun alààyè run pátápátá, gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run ẹli, ti pàṣẹ. Joṣua sì ṣẹ́gun wọn láti ṣi- sí àti láti gbogbo agbègbè Goṣeni lọ sí . Gbogbo àwọn ọba wọ̀nyí àti ilẹ̀ wọn ní Joṣua ṣẹ́gun ní ìwọ́de ogun ẹ̀ẹ̀kan, nítorí tí Olúwa, Ọlọ́run ẹli, jà fún ẹli. Nígbà náà ni Joṣua padà sí ibùdó ní pẹ̀lú gbogbo ẹli.

Every verse in Joshua 10

Chapter navigation

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.

0:000:00