Joshua 12:21
“ọba Taanaki, ọ̀kan ọba Megido, ọ̀kan”
Joshua 12:21 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 21 of 24 in Joshua chapter 12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Joshua 12 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí àwọn ará ẹli ṣẹ́gun, tí wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn ní ìlà-oòrùn , láti odò dé òkè , pẹ̀lú gbogbo ìhà ìlà-oòrùn aginjù: Sihoni ọba àwọn , tí ó jẹ ọba ní Heṣboni. Ó ṣe àkóso láti tí ń bẹ ní etí odò , láti ìlú tó wà ní àárín àfonífojì náà dé odò , èyí tí ó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ . Pẹ̀lú ìdajì àwọn ará . Ó sì ṣe àkóso ní orí ìlà-oòrùn aginjù láti Òkun sí ìhà Òkun ti aginjù (ti o túmọ̀ sí Òkun Iyọ̀), sí -Jeṣimoti, àti láti gúúsù lọ dé ìsàlẹ̀ ẹsẹ̀ òkè . Àti agbègbè ọba Baṣani, ọ̀kan nínú àwọn tí ó kù nínú àwọn ará , ẹni tí ó jẹ ọba ní Aṣtarotu àti . Ó ṣe àkóso ní orí òkè , Saleka, Baṣani títí dé ààlà àwọn ènìyàn Geṣuri àti , àti ìdajì dé ààlà ọba Heṣboni. Mose ìránṣẹ́ Olúwa àti àwọn ọmọ ẹli sì borí wọn. Mose ìránṣẹ́ Olúwa sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà , àwọn ẹ̀yà àti ìdajì ẹ̀yà kí ó jẹ́ ohun ìní wọn. Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Joṣua àti àwọn ọmọ ẹli ṣẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn , láti - ní àfonífojì sí òkè , èyí tí o lọ sí ọ̀nà (Joṣua sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà ẹli ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn: ilẹ̀ òkè, ní ẹsẹ̀ òkè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn òkè aginjù, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aginjù àti nì gúúsù ilẹ̀ àwọn ará: Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti àwọn ará ). Ọba , ọ̀kan ọba (tí ó wà nítòsí ), ọ̀kan ọba ẹmu, ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba ṣi, ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba Laṣaroni, ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba Ṣimroni-, ọ̀kan ọba Akṣafu, ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kan ọba ṣi, ọ̀kan ọba ni , ọ̀kan ọba (ní ), ọ̀kan ọba ní , ọ̀kan ọba , ọ̀kan. Gbogbo àwọn ọba náà jẹ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n.
Every verse in Joshua 12
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.