“Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Joṣua àti àwọn ọmọ Israẹli ṣẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn Jordani, láti Baali-Gadi ní àfonífojì Lebanoni sí òkè Halaki, èyí tí o lọ sí ọ̀nà Seiri (Joṣua sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Israẹli ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn:”
Joṣua 12:7 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 7 of 24 in Joṣua chapter 12 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Joṣua 12 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí àwọn ará ẹli ṣẹ́gun, tí wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn ní ìlà-oòrùn , láti odò dé òkè , pẹ̀lú gbogbo ìhà ìlà-oòrùn aginjù:Sihoni ọba àwọn , tí ó jẹ ọba ní Heṣboni. Ó ṣe àkóso láti tí ń bẹ ní etí odò , láti ìlú tó wà ní àárín àfonífojì náà dé odò , èyí tí ó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ . Pẹ̀lú ìdajì àwọn ará .Ó sì ṣe àkóso ní orí ìlà-oòrùn aginjù láti Òkun sí ìhà Òkun ti aginjù (ti o túmọ̀ sí Òkun Iyọ̀), sí -Jeṣimoti, àti láti gúúsù lọ dé ìsàlẹ̀ ẹsẹ̀ òkè .Àti agbègbè ọba Baṣani, ọ̀kan nínú àwọn tí ó kù nínú àwọn ará , ẹni tí ó jẹ ọba ní Aṣtarotu àti .Ó ṣe àkóso ní orí òkè , Saleka, Baṣani títí dé ààlà àwọn ènìyàn Geṣuri àti , àti ìdajì dé ààlà ọba Heṣboni.Mose ìránṣẹ́ Olúwa àti àwọn ọmọ ẹli sì borí wọn. Mose ìránṣẹ́ Olúwa sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà , àwọn ẹ̀yà àti ìdajì ẹ̀yà kí ó jẹ́ ohun ìní wọn.Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Joṣua àti àwọn ọmọ ẹli ṣẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn , láti - ní àfonífojì sí òkè , èyí tí o lọ sí ọ̀nà (Joṣua sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà ẹli ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn:ilẹ̀ òkè, ní ẹsẹ̀ òkè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn òkè aginjù, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aginjù àti nì gúúsù ilẹ̀ àwọn ará: Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti àwọn ará ).Ọba , ọ̀kan ọba (tí ó wà nítòsí ), ọ̀kanọba ẹmu, ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba ṣi, ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba Laṣaroni, ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba Ṣimroni-, ọ̀kan ọba Akṣafu, ọ̀kanọba , ọ̀kan ọba , ọ̀kanọba ṣi, ọ̀kan ọba ni , ọ̀kanọba (ní ), ọ̀kan ọba ní , ọ̀kanọba , ọ̀kan. Gbogbo àwọn ọba náà jẹ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n.