Numbers 32:15
“Tí ẹ̀yin bá yípadà ní ẹ̀yìn rẹ̀ yóò sì fi àwọn ènìyàn wọ̀nyí sílẹ̀ ní aginjù, ìwọ yóò sì mú un ṣe ìparun.””
Numbers 32:15 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
Verse 15 of 42 in Numbers chapter 32 — Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible. Read it in context below, with maps, timelines and thematic connections beside the text.
Numbers 32 — full chapter (Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible)
Àwọn ọmọ àti àwọn ọmọ , tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn àti ohun ọ̀sìn rí wí pé ilẹ̀ àti dára fún ohun ọ̀sìn. Àwọn ọmọ àti àwọn ọmọ sì wá, wọ́n wá sí ọ̀dọ̀ àti àlùfáà àti sí olórí gbogbo ìlú, wọ́n sì wí pé, “Atarotu, Diboni, Jaseri, Nimra, Heṣboni, Eleale, Sebamu, Nebo, àti . Ni ilẹ̀ tí Olúwa ti ṣẹ́gun níwájú ìjọ ẹli tí ó sì dára fún ohun ọ̀sìn, ṣáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì ní ohun ọ̀sìn.” Wọ́n wí pé, “Tí a bá rí ojúrere rẹ, jẹ́ kí a fi ilẹ̀ yìí fún ìránṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí ìní. Má ṣe jẹ́ kí a rékọjá odò .” Mose sọ fún àwọn ọmọ àti fún ọmọ pé, “Ṣé kí àwọn arákùnrin yín lọ sí ogun, kí ẹ̀yin kí ó sì jókòó sí bí? Kí ni ó dé tí o fi mú ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ọmọ ẹli láti lọ sí ibi ilẹ̀ tí Olúwa ti fi fún wọn? Èyí ni nǹkan tí baba yín ṣe nígbà tí mo rán wọn láti ṣi- láti lọ wo ilẹ̀ náà. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n lọ sí àfonífojì Eṣkolu tí wọ́n rí ilẹ̀ náà, wọ́n mú ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ọmọ ẹli láti wọ ilẹ̀ tí Olúwa ti fi fún wọn. Ìbínú Olúwa sì dìde sí wọn ní ọjọ́ náà, ó sì búra, wí pé, ‘Nítorí wọn kò tẹ̀lé mi tọkàntọkàn, kì í ṣe ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin náà tí ó jẹ́ ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ tí ó gòkè láti ni yóò rí ilẹ̀ tí mo pinnu gẹ́gẹ́ bí ìbúra fún , fún àti fún ọbu: kò sí ẹnìkankan àyàfi ọmọ ti àti Joṣua ọmọ , nítorí wọ́n tẹ̀lé Olúwa tọkàntọkàn.’ Ìbínú Olúwa ru sí àwọn ọmọ ẹli ó sì mú wọn rìn ní aginjù fún ogójì ọdún, títí tí àwọn ìran tí wọ́n ṣe búburú ní ojú rẹ̀ fi lọ. “Níbí ni ẹ̀yin wà, ẹ̀yin ẹlẹ́ṣẹ̀, ẹ̀yin dìde ní ipò baba yín, ẹ sì jẹ́ kí ìbínú gbígbóná Olúwa ru sí ẹli. Tí ẹ̀yin bá yípadà ní ẹ̀yìn rẹ̀ yóò sì fi àwọn ènìyàn wọ̀nyí sílẹ̀ ní aginjù, ìwọ yóò sì mú un ṣe ìparun.” Nígbà náà wọ́n wá sí òkè ní ọ̀dọ̀ rẹ̀, “Àwa yóò fẹ́ láti kọ́ ilé ẹran níhìn-ín yìí fún ohun ọ̀sìn wa, àti ìlú fún àwọn obìnrin àti ọmọ wẹ́wẹ́ wa. Ṣùgbọ́n àwa ṣetán láti dira ogun ṣáájú àwọn ọmọ ẹli títí tí a yóò fi mú wọn dé ọ̀dọ̀ wọn lákokò yìí, àwọn obìnrin àti ọmọ wẹ́wẹ́ wa yóò gbé inú ìlú tí a mọ odi sí fún ìdáàbòbò wọn lọ́wọ́ olùgbé ilẹ̀ náà. A kì yóò padà sí ilẹ̀ wa láìṣe pé gbogbo àwọn ọmọ ẹli ti gba ogún wọn. A kì yóò gba ogún kankan pẹ̀lú wọn ní òdìkejì , nítorí ogún ti wa, ti wá sí ọ̀dọ̀ wa ní ìhà ìlà-oòrùn .” Nígbà náà ni sọ fún wọn pé, “Tí ẹ̀yin yóò bá pa ara yín lára, níwájú Olúwa fún ogún. Bí gbogbo yín yóò bá lọ sí ní ìhámọ́ra níwájú Olúwa, títí yóò fi lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ kúrò níwájú rẹ̀. Tí a ó sì fi ṣe ilẹ̀ náà níwájú Olúwa; ẹ̀yin lè padà tí yóò sì di òmìnira lọ́wọ́ ìdè níwájú Olúwa àti ẹli. Ilẹ̀ yìí yóò sì jẹ́ tiyín níwájú Olúwa. “Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá kọ̀ láti ṣe èyí, ẹ̀yin yóò máa dẹ́ṣẹ̀ sí Olúwa; kí ẹ̀yin kí ó sì mọ̀ dájú pé ẹ̀ṣẹ̀ yín yóò fi yín hàn. Ẹ kọ́ ilé fún àwọn obìnrin yín àti ọmọ wẹ́wẹ́ yín, àti ilé fún agbo ẹran yín, ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó ṣe ohun tí ẹ ti pinnu.” Àwọn ọmọ àti ọmọ sọ fún pé, “Àwa ìránṣẹ́ rẹ yóò ṣe gẹ́gẹ́ bí olúwa wa ti pàṣẹ. Àwọn ọmọ wa àti ìyàwó wa, àwọn agbo ẹran àti ohun ọ̀sìn wa yóò dúró ní ìlú . Ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ rẹ, gbogbo ọkùnrin tí ó wọ ìhámọ́ra ogun, yóò rékọjá lọ láti jà níwájú Olúwa; gẹ́gẹ́ bí olúwa wa ti sọ.” Nígbà náà ni pàṣẹ nípa wọn fún àlùfáà àti Joṣua ọmọ àti sí gbogbo olórí ìdílé ẹ̀yà ẹli. Mose sì wí fún wọn pé, “Tí àwọn ọmọ àti ọmọ , gbogbo ọkùnrin tí ó wọ ìhámọ́ra fún ogun rékọjá odò pẹ̀lú níwájú Olúwa, nígbà tí ẹ ṣẹ́gun ilẹ̀ náà níwájú yín, fún wọn ní ilẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìní wọn. Ṣùgbọ́n tí wọn kò bá fẹ́ bá yín rékọjá pẹ̀lú ìhámọ́ra, wọn gbọdọ̀ gba ìní wọn pẹ̀lú yín ní .” Àwọn ọmọ àti ọmọ dáhùn pé, “Ìránṣẹ́ rẹ yóò ṣe ohun tí Olúwa ti sọ. A máa rékọjá níwájú Olúwa lọ sí pẹ̀lú ìhámọ́ra, ṣùgbọ́n ẹrù tí a jogún yóò wà ní ẹ̀bá .” Nígbà náà fún àwọn ọmọ àti àwọn ọmọ àti ààbọ̀ ẹ̀yà ọmọ ẹfu ní ilẹ̀ ọba ọba àwọn ọmọ àti ilẹ̀ ọba ọba Baṣani ní gbogbo ilẹ̀ náà pẹ̀lú ìlú rẹ̀ àti agbègbè tí ó yí i ka. Àwọn ará wọ́n kọ́ , Atarotu, Aroeri; pẹ̀lú Ṣofani, Jaseri, àti , pẹ̀lú -, àti - ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn. Àwọn ọmọ sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu, pẹ̀lú pẹ̀lú - (wọ́n pàrọ̀ orúkọ wọn) àti . Wọ́n sì sọ ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ mìíràn. Àwọn ọmọ ọmọ lọ sí , wọ́n sì lé àwọn ọmọ tí ó wà níbẹ̀. Mose sì fi àwọn ọmọ fún àwọn ọmọ àwọn ìran , wọ́n sì tẹ̀dó síbẹ̀. Jairi, ọmọ gba ibùjókòó wọn, ó sì pè wọ́n ní . Noba gba àti àwọn ìtẹ̀dó rẹ̀, ó sì pè é ní lẹ́yìn orúkọ ara rẹ̀.
Every verse in Numbers 32
Chapter navigation
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ / Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission. Licensed under CC BY-SA 4.0.